Lẹ́yìn Ọlọ́run Olódùmarè, Yorùbá Ni!
ìdàgbàsókè àti ìsòwọpọ orílè-èdè Yorùbá
Ìdí Tí O Ṣe Nílò Làti Darapọ Mọ Ààyè Ayélujára Tí Ọmọ Bíbí Orílè-Èdè Yorùbá
Ànfàní Tí O Wá Nínú Didarapọ
Orí àgbàgbé yí wa fún gbogbo ọmọ káarọ o jire fún ìdàgbàsókè àti ìsòwọpọ orílè-èdè Yorùbá. Kí ibasepo to dán mọran bá le wa láàárín wa; yálà o wá ní ilẹ̀ Yorùbá tàbí o wá ní oke-okùn.
Ànfàní Tí O Wá Nínú Didarapọ
Gbà Ẹ̀bùn Nípa Kí Kópa Lórí Àwọn Ọrọ Tíó Ṣe Pàtàkì Àti Pínpín Ọrọ Tí O Le Gbani Níyànjú Àti Títẹ Atẹjade Ọrọ L'oríṣiríṣi Tí O Le La Ọpọlọpọ Àwọn Ènìyàn L'ójú
F'orúkọsilẹ fún ànfàní làti léè darapọ̀ mọ́ wa. Orí àgbàgbé yí wa fún gbogbo ọmọ káarọ o'jire fún ìdàgbàsókè, ìsòwọpọ àti ibasepọ to dánmọran bá le wa láàárín wa; yálà o wá ní ilẹ̀ Yorùbá tàbí o wá ní oke-okùn.
or
No apps configured. Please contact your administrator.
Already have an account?Login