Ẹ MÁA BÁ WA YỌ ÌDÁMẸ́WA TÀÀRÀ LÁTI OWÓ OṢÙ ÒṢÌṢẸ — BÍṢỌ́BÙ PA’RỌWÀ SÍ ÌJỌBA!
Ákí bísọ́bù sọ wípé kí ìjọba àpapọ̀ ìlú Ajíríyà máa yọ ìdáméwàá kúrò nínú owó osù àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba kí wọn tó san ọwó oṣù. Hmmmm. Orísìíríṣìí, ìyàwó elégún; bí a ṣe ń rí gígùn là ń rí kúkúrú; bí a ṣe ń rí tínrín là ń rí ọ̀rọ̀bọ̀; bí a ṣe ń rí gíga […]